Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ruth: Becomes an ancestor of Jesus 3 ẹsẹ · 8 abala Wá "Ruth" Gbogbo 48 Receives kindness from Boaz 15 Her devotion to Naomi 13 Under Naomi's instructions claims from Boaz the duty of a kinsman 9 Marries Boaz 5 Becomes an ancestor of Jesus 3 Goes to Bethlehem 2 Gleaned in the field of Boaz 1 The daughter-in-law of Naomi 1 Àwọn ẹsẹ nípa Becomes an ancestor of Jesus Rutu 4:13Báyìí ni Boasi ṣe mú Rutu, tí ó sì di aya rẹ̀. Nígbà náà ni ó wọlé tọ aya rẹ̀, Olúwa sì mú kí ó lóyún, ó sì bí ọmọ ọkùnrin kan.Rutu 4:21Salmoni ni baba Boasi, Boasi ni baba Obedi,Rutu 4:22Obedi ní baba Jese, Jese ni baba Dafidi.