Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ruby

4 ẹsẹ

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. A kò lè dárúkọ iyùn tàbí òkúta jasperi; iye ọgbọ́n sì ju iyùn lọ.

  2. Wúrà wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹ, ṣùgbọ́n, ahọ́n tí ń sọ ìmọ̀ gan an ni ọ̀ṣọ́ iyebíye.

  3. Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ.

  4. Ọmọ ọba ọkùnrin wọn mọ́ ju òjò-dídì, wọ́n sì funfun ju wàrà lọ wọ́n ni ìtọ́jú bí iyùn pupa, ìrísí wọn dàbí safire.