Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reptiles: Placed under the dominion of man

1 ẹsẹ · 21 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Placed under the dominion of man

  1. Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ bí àwa ti rí, kí wọn kí ó jẹ ọba lórí ẹja òkun, ẹyẹ ojú ọ̀run, ẹran ọ̀sìn, gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo tí ń rìn lórí ilẹ̀.”