Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rehob: 1. Father of Hadadezer, king of Zobah

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Father of Hadadezer, king of Zobah

  1. Dafidi sì kọlu Hadadeseri ọmọ Rehobu, ọba Soba, bí òun sì ti ń lọ láti mú agbára rẹ̀ bọ̀ sípò ni odò Eufurate.

  2. Lọ́wọ́ Siria àti lọ́wọ́ Moabu àti lọ́wọ́ àwọn ọmọ Ammoni, àti lọ́wọ́ àwọn Filistini, àti lọ́wọ́ Amaleki, àti nínú ìkógun Hadadeseri ọmọ Rehobu ọba Soba.