Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ramoth: 2. Called Ramath of the South, a place probably in the south of Simeon
Àwọn ẹsẹ nípa 2. Called Ramath of the South, a place probably in the south of Simeon
àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù). Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé.
Ó sì rán an sí àwọn tí ó wà ni Beteli àti sí àwọn tí ó wà ní gúúsù tí Ramoti, àti sí àwọn tí ó wà ní Jattiri.