Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rameses: City of, built by the Israelites as a treasure city for Pharaoh
Àwọn ẹsẹ nípa City of, built by the Israelites as a treasure city for Pharaoh
Nítorí náà, wọ́n yan àwọn ọ̀gá akóniṣiṣẹ́ lé wọn lórí láti máa ni wọ́n lára pẹ̀lú iṣẹ́ àṣekára. Wọ́n sì kọ́ Pitomi àti Ramesesi gẹ́gẹ́ bí ìlú ìṣúra pamọ́ sí fún Farao.