Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rabsaris: 2. An Assyrian prince in time of Nebuchadnezzar, or possibly, a second name given to Nebushasban
Àwọn ẹsẹ nípa 2. An Assyrian prince in time of Nebuchadnezzar, or possibly, a second name given to Nebushasban
Nígbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli wá, wọ́n sì jókòó ní àárín ẹnu ibodè, àní Nergali-Ṣareseri ti Samgari, Nebo-Sarsikimu olórí ìwẹ̀fà, Nergali-Ṣareseri, olórí amòye, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli yóò kú.
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú, Nebusaradani balógun ìṣọ́, àti Nebusaradani olórí ìwẹ̀fà, àti Nergali-Ṣareseri, olórí amòye àti gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli,