Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rabsaris: 1. An Assyrian officer. Sent by Sennacherib against Jerusalem

1 ẹsẹ · 2 abala

Wá "Rabsaris"

Àwọn ẹsẹ nípa 1. An Assyrian officer. Sent by Sennacherib against Jerusalem

  1. Ọba Asiria rán alákòóso gíga jùlọ, ìjòyè pàtàkì àti àwọn adarí pápá pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun tí ó pọ̀, láti Lakiṣi sí ọba Hesekiah ní Jerusalẹmu. Wọ́n wá sí òkè Jerusalẹmu wọ́n sì dúró ní etí ìdarí omi àbàtà òkè, ní ojú ọ̀nà tó lọ sí òpópó pápá alágbàfọ̀.