Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prayer Under Affliction: For mitigation of troubles

2 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa For mitigation of troubles

  1. “Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa, kí o sì fetí sí igbe mi; kí o má ṣe di etí rẹ sí ẹkún mi. Nítorí àlejò ni èmi lọ́dọ̀ rẹ, àti àtìpó, bí gbogbo àwọn baba mi ti rí.

  2. Dá mi sí, kí èmi lè ní agbára, kí èmi tó lọ kúrò níhìn-ín yìí, àti kí èmi ó tó ṣe aláìsí.”