Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Phylactery: Worn ostentatiously by the Jews, on the head and left arm
Àwọn ẹsẹ nípa Worn ostentatiously by the Jews, on the head and left arm
“Ohun gbogbo tí wọ́n ń ṣe, wọ́n ń ṣe é kí àwọn ènìyàn ba à lè rí wọn ni. Wọ́n ń sọ filakteri wọn di gbígbòòrò. Wọ́n tilẹ̀ ń bùkún ìṣẹ́tí aṣọ oyè wọn nígbà gbogbo kí ó ba à lè máa tóbi sí i.