Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Philippi: Paul sends Epaphroditus to
Àwọn ẹsẹ nípa Paul sends Epaphroditus to
Mo kà á sí pé n kò lè ṣàìrán Epafiroditu arákùnrin mi sí yín, àti olùbáṣiṣẹ́ pọ̀ mi, àti ọmọ-ogun ẹlẹgbẹ́ mi, ìránṣẹ́ yín pẹ̀lú, tí ẹ rán láti ṣè ránṣẹ́ fún mi nínú àìní mi.