Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Peace Offerings: By Joshua after his victories

1 ẹsẹ · 38 abala

Àwọn ẹsẹ nípa By Joshua after his victories

  1. gẹ́gẹ́ bí Mose ìránṣẹ́ Olúwa ti pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli. Ó sì kọ́ ọ́ gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ nínú ìwé òfin Mose, pẹpẹ odindi òkúta, èyí tí ẹnìkan kò fi ohun èlò irin kàn rí. Wọ́n sì rú ọrẹ ẹbọ sísun àti ọrẹ àlàáfíà ní orí rẹ̀ sí Olúwa.