Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Peace Offerings: By David on bringing up the ark
Àwọn ẹsẹ nípa By David on bringing up the ark
Wọ́n sì mú àpótí ẹ̀rí Olúwa náà wá, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sípò rẹ̀ láàrín àgọ́ náà tí Dafidi pa fún un. Dafidi sì rú ẹbọ sísun àti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ níwájú Olúwa.