Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Patience: Waiting for the hope of the gospel
Àwọn ẹsẹ nípa Waiting for the hope of the gospel
Ṣùgbọ́n bí àwa bá ń retí èyí tí àwa kò rí, ǹjẹ́ àwa ń fi sùúrù dúró dè é.
Nítorí nípa Ẹ̀mí àwa ń fi ìgbàgbọ́ dúró de ìrètí òdodo.