Skip to content

Patmos

1 verse

37.3000, 26.5400 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Patmos

  1. Èmi, Johanu, arákùnrin yín àti alábápín pẹ̀lú yín nínú wàhálà àti ìjọba àti sùúrù tí ń bẹ nínú Jesu, wà ní erékúṣù tí a ń pè ní Patmo, nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, àti nítorí ẹ̀rí Jesu Kristi.