Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Patience: Suffering with, for well-doing, is acceptable with God
Àwọn ẹsẹ nípa Suffering with, for well-doing, is acceptable with God
Ṣùgbọ́n ògo kín ni ó jẹ́, nígbà tí ẹ ba ṣẹ̀ tí a sì lù yín, bí ẹ bá fi sùúrù gbà á? Ṣùgbọ́n nígbà tí ẹ̀yin bá ń ṣe rere tí ẹ sì ń jìyà, bí ẹ bá fi sùúrù gbà á, ẹ̀yín ní ọpẹ́ lọ́dọ̀ Ọlọ́run.