Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paran: David takes refuge in
Àwọn ẹsẹ nípa David takes refuge in
Samuẹli sì kú; gbogbo ènìyàn Israẹli sì kó ara wọn jọ, wọ́n sì sọkún rẹ̀ wọ́n sì sin ín nínú ilé rẹ̀ ní Rama. Dafidi sì dìde, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ijù Parani.