Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nethinim: The remnant of the Canaanites appointed as, by Solomon

3 ẹsẹ · 8 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The remnant of the Canaanites appointed as, by Solomon

  1. Gbogbo ènìyàn tí ó kù nínú àwọn ará Amori ará Hiti, Peresi, Hifi àti Jebusi, àwọn ènìyàn wọ̀nyí kì í ṣe ará Israẹli,

  2. ìyẹn ni pé àwọn ọmọ wọn tí ó kù ní ilẹ̀ náà, tí àwọn ọmọ Israẹli kò le parun pátápátá, àwọn ni Solomoni bu iṣẹ́ ẹrú fún títí di òní yìí.

  3. Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni jẹ́ irinwó ó dín mẹ́jọ (392).