Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nemuel: 2. A son of Simeon
Àwọn ẹsẹ nípa 2. A son of Simeon
Àwọn ọmọ ìran Simeoni bí ìdílé wọn: ti Nemueli, ìdílé Nemueli; ti Jamini, ìdílé Jamini; ti Jakini, ìdílé Jakini;
Àwọn ọmọ Simeoni: Nemueli, Jamini, Jaribi, Sera àti Saulu;