Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nazarites: To bring two turtle doves for a burnt offering

2 ẹsẹ · 20 abala

Àwọn ẹsẹ nípa To bring two turtle doves for a burnt offering

  1. Ní ọjọ́ kẹjọ, yóò mú àdàbà méjì àti ọmọ ẹyẹlé méjì wá sọ́dọ̀ àlùfáà ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

  2. Àlùfáà yóò fi ọ̀kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti èkejì fún ẹbọ sísun láti fi ṣe ètùtù fún un nítorí pé ó ti ṣẹ̀ nípa wíwà níbi tí òkú ènìyàn wà. Yóò sì ya orí rẹ̀ sí mímọ́ ní ọjọ́ náà gan an.