Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nahshon: Son of Amminadab
Àwọn ẹsẹ nípa Son of Amminadab
Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbìnrin Amminadabu tí í ṣe arábìnrin Nahiṣoni, ó sì bí Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.
Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu.
Ramu sì ni baba Amminadabu, àti Amminadabu baba Nahiṣoni olórí àwọn ènìyàn Juda.