Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Naashon: In the lineage of Christ 2 ẹsẹ · 2 abala Wá "Naashon" Gbogbo 8 A captain of Judah's host 6 In the lineage of Christ 2 Àwọn ẹsẹ nípa In the lineage of Christ Matiu 1:4Ramu ni baba Amminadabu; Amminadabu ni baba Nahiṣoni; Nahiṣoni ni baba Salmoni;Luku 3:32tí í ṣe ọmọ Jese, tí í ṣe ọmọ Obedi, tí í ṣe ọmọ Boasi, tí í ṣe ọmọ Salmoni, tí í ṣe ọmọ Nahiṣoni,