Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moth: Figurative

3 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Figurative

  1. “Má ṣe to àwọn ìṣúra jọ fún ara rẹ ní ayé yìí, níbi tí kòkòrò ti le jẹ ẹ́, tí ó sì ti le bàjẹ́ àti ibi tí àwọn olè lè fọ́ tí wọ́n yóò sì jí i lọ.

  2. Dípò bẹ́ẹ̀ to ìṣúra rẹ jọ sí ọ̀run, níbi ti kòkòrò àti ìpáàrà kò ti lè bà á jẹ́, àti ní ibi tí àwọn olè kò le fọ́ wọlé láti jí í lọ.

  3. Ọrọ̀ yín díbàjẹ́, kòkòrò sì ti jẹ aṣọ yín.