Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Modern Judea: Often left, to escape persecution
Àwọn ẹsẹ nípa Often left, to escape persecution
Àwọn Farisi sì gbọ́ pé, Jesu ni, ó sì ń ṣe ìtẹ̀bọmi fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀ ju Johanu lọ.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Jesu tìkára rẹ̀ kò ṣe ìtẹ̀bọmi bí kò ṣe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀,
Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili.