Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mill: Upper and nether stones of

3 ẹsẹ · 5 abala

Wá "Mill"

Àwọn ẹsẹ nípa Upper and nether stones of

  1. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ gba ìyá ọlọ tàbí ọmọ ọlọ gẹ́gẹ́ bí ohun ìdúró fún gbèsè, nítorí pé ẹ̀mí ènìyàn ni ó gbà ní pàṣípàrọ̀ n nì.

  2. Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta, àní, ó le bi ìyá ọlọ.

  3. Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun; mú ìbòjú rẹ kúrò. Ká aṣọ ẹsẹ̀ rẹ sókè, ká aṣọ itan, kí o sì la odò wọ̀n-ọn-nì kọjá.