Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Medeba: An idolatrous high place
Àwọn ẹsẹ nípa An idolatrous high place
Diboni gòkè lọ sí tẹmpili rẹ̀, sí àwọn ibi gíga rẹ̀ láti sọkún, Moabu pohùnréré lórí Nebo àti Medeba. Gbogbo orí ni a fá gbogbo irùngbọ̀n ni a gé dànù.