Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Manna: Figurative
Àwọn ẹsẹ nípa Figurative
Èmi ni oúnjẹ ìyè.
Àwọn baba yín jẹ manna ní aginjù, wọ́n sì kú.
Èyí ni oúnjẹ tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, kí ènìyàn lè máa jẹ nínú rẹ̀ kí ó má sì kú.
Èmi ni oúnjẹ ìyè náà tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, bí ẹnikẹ́ni bá jẹ nínú oúnjẹ yìí, yóò yè títí láéláé, oúnjẹ náà tí èmi ó sì fi fún ni fún ìyè aráyé ni ara mi.”