Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Kirjath-Sepher: General references

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa General references

  1. Ó sì wọ́de ogun láti ibẹ̀ lọ bá àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Debiri (tí à ń pè ní Kiriati-Seferi nígbà kan rí).

  2. Kalebu sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọbìnrin mi Aksa fún ọkùnrin tí ó bá kọlu Kiriati-Seferi, tí ó sì gbà á ní ìgbéyàwó.”