Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jonah: Sent by God to warn Nineveh 2 ẹsẹ · 7 abala Wá "Jonah" Gbogbo 50 Disobedience and punishment of 15 Displeased with God's mercy to Nineveh; reproved 11 Brought Ninevites to repentance 10 Repentance and deliverance of 10 Is a sign 2 Sent by God to warn Nineveh 2 A prophet of Israel · Àwọn ẹsẹ nípa Sent by God to warn Nineveh Jona 1:1Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Jona ọmọ Amittai wá, wí pé:Jona 1:2“Dìde lọ sí ìlú ńlá Ninefe kí o sì wàásù sí i, nítorí ìwà búburú rẹ̀ gòkè wá iwájú mi.”