Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Iron

3 ẹsẹ · 40 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Eleasari àlùfáà sì wí fún àwọn olórí ogun náà pé, “Èyí ní ìlànà òfin tí Olúwa fi lélẹ̀ ní àṣẹ fún Mose.

  2. Kìkì i wúrà, fàdákà, idẹ, irin, idẹ àti òjé.

  3. Ohunkóhun tí ó lè la iná ni kí ẹ̀yin ó mú la iná, nígbà náà ni yóò jẹ́ mímọ́. Ṣùgbọ́n ẹ yóò fi omi ìyàsímímọ́ sọ ọ́ di mímọ́. Àti gbogbo ohun tí kò lè la iná kọjá ni kí a mú la inú omi.