Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Instruction: General references
Àwọn ẹsẹ nípa General references
Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn;
ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà.
Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí;
oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi,
òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.