Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Eshcol: 2. A valley or brook near Hebron

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. A valley or brook near Hebron

  1. Nígbà tí wọ́n dé àfonífojì Eṣkolu, wọ́n gé ẹ̀ka kan tó ní ìdì èso àjàrà gireepu kan. Àwọn méjì sì fi ọ̀pá kan gbé e; wọ́n tún mú èso pomegiranate àti èso ọ̀pọ̀tọ́ pẹ̀lú.

  2. Wọ́n sì sọ ibẹ̀ ní àfonífojì Eṣkolu nítorí ìdì èso gireepu tí àwọn ọmọ Israẹli gé níbẹ̀.