Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Demons: Testify to the divinity of Jesus

2 ẹsẹ · 15 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Testify to the divinity of Jesus

  1. Ní àsìkò náà gan an ni ọkùnrin kan tí ó wà nínú Sinagọgu wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́, bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe wí pé,

  2. “Kí ni ìwọ ń wá lọ́dọ̀ wa, Jesu ti Nasareti? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!”