Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Compared To Saints: Good fishes
Àwọn ẹsẹ nípa Good fishes
Nígbà tí àwọ̀n náà sì kún, àwọn apẹja fà á sókè sí etí bèbè Òkun, wọ́n jókòó, wọ́n sì ṣa àwọn èyí tí ó dára sínú apẹ̀rẹ̀, ṣùgbọ́n wọ́n da àwọn tí kò dára nù.