Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Compared To Saints: Gold

2 ẹsẹ · 46 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Gold

  1. Ṣùgbọ́n òun mọ ọ̀nà tí èmi ń tọ̀, nígbà tí ó bá dán mí wò, èmi yóò jáde bí wúrà.

  2. Báwo ni àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Sioni tí ó ṣe iyebíye, tí wọ́n fi wúrà dídára ṣe wá dàbí ìkòkò amọ̀ lásán iṣẹ́ ọwọ́ amọ̀kòkò!