Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Census: Of the Roman empire, by Caesar 3 ẹsẹ · 2 abala Wá "Census" Gbogbo 8 A poll tax to be levied at each 5 Of the Roman empire, by Caesar 3 Àwọn ẹsẹ nípa Of the Roman empire, by Caesar Luku 2:1Ó sì ṣe ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àṣẹ ti ọ̀dọ̀ Kesari Augustu jáde wá pé, kí a kọ orúkọ gbogbo ayé sínú ìwé.Luku 2:2(Èyí ni ìkọ sínú ìwé èkínní tí a ṣe nígbà tí Kirene fi jẹ baálẹ̀ Siria.)Luku 2:3Gbogbo àwọn ènìyàn sì lọ láti kọ orúkọ wọn sínú ìwé, olúkúlùkù sí ìlú ara rẹ̀.