Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Boil: Of Job 2 ẹsẹ · 5 abala Wá "Boil" Gbogbo 10 Levitical ceremonies prescribed for 6 Of Job 2 Plague of Egyptians 2 Of Hezekiah, healed · Plague of the Philistines · Àwọn ẹsẹ nípa Of Job Jobu 2:7Bẹ́ẹ̀ ni Satani jáde lọ kúrò níwájú Olúwa, ó sì sọ Jobu ní oówo kíkankíkan láti àtẹ́lẹsẹ̀ títí dé àtàrí rẹ̀.Jobu 2:8Ó sì mú àpáàdì, ó fi ń họ ara rẹ̀, ó sì jókòó nínú eérú.