Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Basket: Received the fragments after the miracles of the loaves

2 ẹsẹ · 3 abala

Wá "Basket"

Àwọn ẹsẹ nípa Received the fragments after the miracles of the loaves

  1. Tàbí ọ̀rọ̀ kò yé yín di ìsinsin yìí? Ẹ̀yin kò rántí pé mo bọ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ènìyàn pẹ̀lú ìṣù àkàrà márùn-ún àti iye agbọ̀n tí ẹ kójọ bí àjẹkù?

  2. Ẹ kò sì tún rántí ìṣù méje tí mo fi bọ́ ẹgbàajì (4,000) ènìyàn àti iye agbọ̀n tí ẹ̀yín kójọ?