Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ancient Samaria: The burial place of the kings of Israel

3 ẹsẹ · 29 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The burial place of the kings of Israel

  1. Omri sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín ní Samaria. Ahabu ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

  2. Bẹ́ẹ̀ ni ọba kú, a sì gbé e wá sí Samaria, wọ́n sì sin ín ní Samaria.

  3. Jehoaṣi sinmi pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀. Jeroboamu sì rọ́pò rẹ̀ lórí ìtẹ́. A sin Jehoaṣi sí Samaria pẹ̀lú àwọn ọba Israẹli.