Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Amariah: 2. Chief priest in the reign of Jehoshaphat

1 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. Chief priest in the reign of Jehoshaphat

  1. “Amariah àlùfáà ni yóò jẹ́ olórí yín nínú gbogbo ọ̀ràn tí ó jẹ́ ti Olúwa, àti Sebadiah ọmọ Iṣmaeli alákòóso ìdílé Juda, ní yóò jẹ́ olórí ní gbogbo ọ̀rọ̀ tí ọba, àti àwọn ará Lefi pẹ̀lú yin yóò sìn gẹ́gẹ́ bí ìjòyè níwájú yín. Ẹ ṣe é pẹ̀lú ìmọ́kànle, Olúwa yóò sì wà pẹ̀lú àwọn tó bá ń ṣe rere.”