Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Amariah: 6. Father of Zechariah
Àwọn ẹsẹ nípa 6. Father of Zechariah
Nígbà tí àwọn ènìyàn tókù nínú àwọn Juda àti Benjamini ń gbé ní Jerusalẹmu). Nínú àwọn ọmọ Juda: Ataiah ọmọ Ussiah ọmọ Sekariah, ọmọ Amariah, ọmọ Ṣefatia, ọmọ Mahalaleli, ìran Peresi;