Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Amalek: Son of Eliphaz

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Son of Eliphaz

  1. Elifasi ọmọ Esau sì tún ní àlè tí a ń pè ní Timna pẹ̀lú, òun ló bí Amaleki fún un. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọ Adah aya Esau.

  2. Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki.