Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Altar of Incense: Top of, surrounded with a crown of gold
Àwọn ẹsẹ nípa Top of, surrounded with a crown of gold
Ìwọ yóò sì bo òkè rẹ̀, gbogbo ìhà rẹ̀ àti ìwo rẹ̀ pẹ̀lú u kìkì wúrà, ìwọ yóò sì ṣe wúrà gbà á yíká.
Kìkì wúrà ni ó fi bo orí rẹ̀, gbogbo ìhà rẹ̀ àti ìwo rẹ̀, ó sì fi ìgbátí wúrà yìí ká.