Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Altar of Incense: Anointed with holy oil
Àwọn ẹsẹ nípa Anointed with holy oil
Ìwọ yóò sì lò ó láti ya àgọ́ sí mímọ́ àti àpótí ẹ̀rí náà,
tábìlì àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, ọ̀pá fìtílà àti ohun èlò rẹ̀, àti pẹpẹ tùràrí,