Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Alexander: 4. A coppersmith

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 4. A coppersmith

  1. Nínú àwọn ẹni tí Himeneu àti Aleksanderu wà; àwọn tí mo ti fi lé Satani lọ́wọ́, kí a lè kọ́ wọn kí wọ́n má sọ̀rọ̀-òdì mọ́.

  2. Aleksanderu alágbẹ̀dẹ bàbà ṣe mi ni ibi púpọ̀: Olúwa yóò san án fún un gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.