Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ahitub: 4. The Ahitub mentioned in 1Chr 6:8; 6:11; 6:12, is probably identical with the last described above, or else he is confused with Azariah, 2Chr 31:10
Àwọn ẹsẹ nípa 4. The Ahitub mentioned in 1Chr 6:8; 6:11; 6:12, is probably identical with the last described above, or else he is confused with Azariah, 2Chr 31:10
Ahitubu baba Sadoku, Sadoku baba Ahimasi,
Asariah baba Amariah Amariah baba Ahitubu
Ahitubu baba Sadoku. Sadoku baba Ṣallumu,
àti Asariah olórí àlùfáà ti ìdílé Sadoku sì dáhùn pé, “Ní ìwọ̀n ìgbà tí àwọn ènìyàn ti bẹ̀rẹ̀ sí ní mú ìdáwó wọn wá sí ilé Olúwa àti ní èyí tí yóò tó jẹ àti ọ̀pọ̀ láti tọ́jú pamọ́ nítorí Olúwa ti bùkún àwọn ènìyàn rẹ̀, ó sì ṣẹ́kù lọ́pọ̀lọ́pọ̀.”