Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Adoption: Solomon
Àwọn ẹsẹ nípa Solomon
Ó wí fún mi pé, Solomoni ọmọ rẹ ni ẹni tí yóò kọ́ ilé mi àti àwọn ààfin mi, nítorí tí èmi ti yàn án láti ṣe ọmọ mi èmi yóò sì jẹ́ baba a rẹ̀.