Kiriathaim
A tún mọ̀ ọ́n sí: Kirjathaim
31.5800, 35.7000 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Kiriathaim
Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu,
Kiriataimu, Sibma, Sereti Ṣahari lórí òkè ní àfonífojì.
Nípa Moabu. Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí: “Ègbé ni fún Nebo nítorí a ó parun. A dójútì Kiriataimu, a sì mú un, ojú yóò ti alágbára, a ó sì fọ́nká.
sórí Kiriataimu, Beti-Gamu àti Beti-Meoni,
nítorí náà, Èmi yóò ṣí Moabu sílẹ̀ láti àwọn ìlú gbogbo tí ó wà ní ààlà rẹ̀, ògo ilẹ̀ náà, Beti-Jeṣimoti, Baali-Meoni àti Kiriataimu.