Ashkenaz
A tún mọ̀ ọ́n sí: Ashchenaz
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Ashkenaz
Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.
Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.
“Gbé àsíá sókè ní ilẹ̀ náà! Fọn ìpè láàrín àwọn orílẹ̀-èdè! Sọ àwọn orílẹ̀-èdè di mímọ́ sórí rẹ̀, pe àwọn ìjọba yìí láti dojúkọ ọ́: Ararati, Minini àti Aṣkenasi. Yan olùdarí ogun láti kọlù ú, rán àwọn ẹṣin sí i bí ọ̀pọ̀ eṣú.