Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Reward of Saints: Beholding the glory of Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Beholding the glory of Christ
“Baba, èmi fẹ́ kí àwọn tí ìwọ fi fún mi, kí ó wà lọ́dọ̀ mi, níbi tí èmi gbé wà; kí wọn lè máa wo ògo mi, tí ìwọ ti fi fún mi, nítorí ìwọ sá à fẹ́ràn mi síwájú ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé.